Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May 1, 2012
© 2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.
Ìsìn Àti Ìṣèlú Ǹjẹ́ Ó Yẹ Ká Dà Wọ́n Pọ̀?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
5 Ojú Wo Ni Jésù Fi Wo Ọ̀rọ̀ Ìṣèlú?
6 Kí Ló Yẹ Kí Àwọn Kristẹni Ṣe Lónìí?
8 Báwo Ni Ẹ̀kọ́ Tí Àwọn Kristẹni Fi Ń Kọ́ni Ṣe Ń Ṣe Àwọn Ará Ìlú Láǹfààní?
10 Onígbàgbọ́ Tòótọ́ àti Ọmọ Ìlú Rere—Béèyàn Ṣe Lè Ṣe Méjèèjì
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
12 Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Pa Dà Máa Fọkàn Tán Ara Yín
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Ìròyìn Ayọ̀ Wo Ló Wà Nípa Ìsìn?
18 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
22 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . . Ǹjẹ́ Àwọn Tó Kọ́kọ́ Bẹ̀rẹ̀ Ẹ̀sìn Kristẹni Lọ́wọ́ Nínú Ìṣèlú?
23 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
24 Ẹ̀kọ́ Bíbélì
31 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Olùsẹ̀san fún Gbogbo Àwọn Tó Ń Sìn Ín
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
26 Kí Lo Lè Ṣe Tí Ọjọ́ Ọ̀la Rẹ Á Fi Dára?
28 Bí Ìgbésí Ayé Ṣe Rí Lákòókò Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì—Àgbẹ̀