ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w12 6/1 ojú ìwé 32
  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
w12 6/1 ojú ìwé 32

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Kí ni àwọn nǹkan tó mú kí Bíbélì yàtọ̀ sí gbogbo àwọn ìwé yòókù?

WO Ọ̀WỌ́ ÀPILẸ̀KỌ TÓ SỌ̀RỌ̀ LÓRÍ KÓKÓ YÌÍ NÍ OJÚ ÌWÉ 4 sí 9.

Tó o bá fẹ́ mọ̀ díẹ̀ nípa ìlú Tẹsalóníkà ìgbàanì àti iṣẹ́ ìwàásù tí Pọ́ọ̀lù ṣe níbẹ̀,

WO OJÚ ÌWÉ 18 sí 21.

Tí owó tó ń wọlé fúnni bá dín kù, kí ni èèyàn lè ṣe tí awọ á fi lè kájú ìlú?

O OJÚ ÌWÉ 22 sí 23.

Ǹjẹ́ àwọn nǹkan kan wà tí àwọn èèyàn máa ń sọ pé kò ṣeé ṣe, àmọ́ tó ṣeé ṣe?

WO OJÚ ÌWÉ 27 sí 29.

[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 32]

Fọ́tò NASA

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́