Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July 1, 2012
© 2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.
Tó O Bá Gbàdúrà, Ta Ló Ń Gbọ́ Àdúrà Rẹ?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Ǹjẹ́ Ẹnì Kan Wà Tó Ń Gbọ́ Àdúrà?
6 Kí Nìdí Tí Olùgbọ́ Àdúrà Fi Fàyè Gba Ìjìyà?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
11 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
12 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Kí Ni Ohun Tí Àwọn Ẹ̀dá Ẹ̀mí Ń Ṣe fún Wa?
18 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Tí Ọlọ́run Bá Ti Dárí Ẹ̀ṣẹ̀ Jini, Ṣé Ó Máa Ń Gbàgbé Rẹ̀?
23 Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—“Ibi Tí O Bá Lọ Ni Èmi Yóò Lọ”
30 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Ọlọ́run Kórìíra Ìwà Ìrẹ́jẹ
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
19 “Nígbàkigbà Tí Ẹ Bá Ń Gbàdúrà, Ẹ Wí Pé, ‘Baba’”