ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w12 7/1 ojú ìwé 32
  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
w12 7/1 ojú ìwé 32

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Tó bá jẹ́ lóòótọ́ ni Ọlọ́run ń gbọ́ àdúrà wa, kí nìdí tó fi fàyè gba ìjìyà?

WO OJÚ ÌWÉ 6 sí 8.

Kí ló jẹ́ kí obìnrin kan nílẹ̀ Philippines jáwọ́ nínú ọtí àmupara, tí ìdílé rẹ̀ fi wá tòrò?

WO OJÚ ÌWÉ 12 sí 13.

Tí Ọlọ́run bá ti dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini, ṣé ó máa ń gbàgbé rẹ̀?

WO OJÚ ÌWÉ 18.

Ẹ̀kọ́ wo ni a lè kọ́ lára Rúùtù obìnrin olóòótọ́ náà nípa ìfẹ́ àti ìdúróṣinṣin?

WO OJÚ ÌWÉ 23 sí 28.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́