Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 1, 2012
© 2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.
Ṣé Iṣẹ́ Ìyanu Ń Ṣẹlẹ̀ Lóòótọ́?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Iṣẹ́ Ìyanu?
4 Ǹjẹ́ Iṣẹ́ Ìyanu Ń Ṣẹlẹ̀ Lóòótọ́?—Ohun Mẹ́ta Táwọn Èèyàn Fi Ń Ta Ko Iṣẹ́ Ìyanu
7 Ǹjẹ́ A Lè Gbà Pé Àwọn Iṣẹ́ Ìyanu inú Bíbélì Ṣẹlẹ̀ Lóòótọ́?
8 Àwọn Iṣẹ́ Ìyanu Tí Wọ́n Máa Tó Ṣẹlẹ̀
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
11 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Ìgbà Wo Ni Jésù Di Ọba?
24 Ẹ̀kọ́ Bíbélì
26 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
27 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Jèhófà Kórìíra Ìwà Ìrẹ́jẹ
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
18 Bí Ìgbésí Ayé Ṣe Rí Lákòókò Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì—Apẹja
21 Ìjíròrò Láàárín Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti Ẹnì Kan—Ṣé Gbogbo Èèyàn Rere Ló Máa Lọ sí Ọ̀run?