Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
December 1, 2012
2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. All rights reserved.
Ohun Kan Wà Tó Dára Ju Kérésìmesì Lọ
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Kí Ló Ń Ṣẹlẹ̀ sí Ohun Tí Ọ̀pọ̀ Gbà Pé Ó Ṣe Pàtàkì Nígbà Kérésì?
5 Rírí Ayọ̀ Látinú Fífúnni Lẹ́bùn
6 Ṣíṣe Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Aláìní
7 Wíwá Àyè Láti Fara Mọ́ Ìdílé
8 Àlàáfíà Láàárín Àwọn Ẹni Tí Inú Ọlọ́run Dùn Sí
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
10 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . . Kí Nìdí Tí Àwọn Kan Kì Í Fi Í Ṣe Kérésìmesì?
11 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ǹjẹ́ Orúkọ Rẹ Wà Nínú “Ìwé Ìrántí” Ọlọ́run?
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Rán Jésù Wá sí Ayé?
21 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
22 Lẹ́tà Kan Láti Orílẹ̀-Èdè Benin
30 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Jótámù Jẹ́ Olóòótọ́ Bó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Bàbá Rẹ̀ Kò Sin Jèhófà Mọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
12 Ní Gbẹ̀yìn Gbẹ́yín Mo Di Òmìnira!
18 Ǹjẹ́ O Rò Pé Èèyàn Máa Ń Tún Ayé Wá?
24 Bí Wọ́n Ṣe Ń Lo Ohun Ìṣaralóge Láyé Ìgbà Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì