Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
January 1, 2013
© 2013 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.
KÓKÓ Ọ̀RỌ̀: ǸJẸ́ Ó YẸ KÉÈYÀN MÁA BẸ̀RÙ ÒPIN AYÉ?
Òpin Ayé Ń Ba Àwọn Kan Lẹ́rù, Ó Ń Wu Àwọn Kan Kó Dé, Ó sì Ti Sú Àwọn Míì 4
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Sún Mọ́ Ọlọ́run—“O . . . Ti Ṣí Wọn Payá fún Àwọn Ìkókó” 9
Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà 10
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—“Bí Ó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Ó Kú, Ó Ń Sọ̀rọ̀ Síbẹ̀” 12
KA ÀPILẸ̀KỌ TÓ KÙ LÓRÍ ÌKÀNNÌ | www.jw.org/yo
ABALA ÀWỌN Ọ̀DỌ́—Má Ṣe Jowú!
Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Míríámù àti Áárónì nígbà tí wọ́n jowú Mósè àbúrò wọn.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ/ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Kọ́ àwọn ọmọdé bí wọ́n ṣe lè máa dúpẹ́ oore.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ/ÀWỌN ỌMỌ)