Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
February 1, 2013
© 2013 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania..
KÓKÓ Ọ̀RỌ̀: KÍ LA LÈ RÍ KỌ́ LÁRA MÓSÈ?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ọlọ́run Àwọn Alààyè Ni 7
Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà 8
Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Ohun Tí Ẹ Lè Ṣe Tí Ọmọ Yín Bá Jẹ́ Abirùn 10
Irú Ìwé Wo Ni “Ìhìn Rere Júdásì”? 13
KA ÀPILẸ̀KỌ TÓ KÙ LÓRÍ ÌKÀNNÌ | www.jw.org/yo
KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ—Ísọ̀
Ìdánrawò. Kí lo mọ̀ nípa Ísọ̀, ẹ̀gbọ́n Jékọ́bù?
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ/ÀWỌN ỌMỌDÉ)
ABALA ÀWỌN Ọ̀DỌ́—Ṣé O Máa Ń Ṣàánú?
Ka ọ̀kan nínú àwọn ìtàn tó gbajúmọ̀ tí Jésù sọ, kí o lè mọ ohun tó kọ́ wa nípa ṣíṣe àánú àti ṣíṣe ẹ̀tanú.