Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May 1, 2013
© 2013 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.
KÓKÓ Ọ̀RỌ̀: ṢÉ ÌKÀ NI ỌLỌ́RUN?
Kí Nìdí Tí Àwọn Èèyàn Fi Ń Sọ Pé Ìkà Ni Ọlọ́run? 3
Ṣé Àwọn Àjálù Tó Ń Ṣẹlẹ̀ Fi Hàn Pé Ìkà Ni Ọlọ́run? 4
Ṣé Àwọn Ìdájọ́ Ọlọ́run Fi Hàn Pé Ìkà Ni? 5
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà 8
Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Bí Àárín Àwọn Tó Tún Ìgbéyàwó Ṣe àti Àwọn Ẹlòmíì Ṣe Lè Tòrò 10
Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ǹjẹ́ Ọ̀rọ̀ Rẹ Jẹ Jèhófà Lógún Lóòótọ́? 14
KA ÀPILẸ̀KỌ TÓ KÙ LÓRÍ ÌKÀNNÌ | www.jw.org/yo
ÀWỌN ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN Ń BÉÈRÈ NÍPA ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ—Ṣé Ẹ Rò Pé Ẹ̀yin Nìkan Ni Ọlọ́run Máa Gbà Là?