Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July 1, 2013
© 2013 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania..
KÓKÓ Ọ̀RỌ̀
ǸJẸ́ Ó YẸ KÍ O GBÁRA LÉ Ẹ̀SÌN?
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí O Yẹ Ẹ̀sìn Rẹ Wò Dáadáa? 3
Ǹjẹ́ O Fara Mọ́ Ọwọ́ Tí Ẹ̀sìn Fi Ń Mú Ọ̀rọ̀ OWÓ? 4
Ǹjẹ́ O Fara Mọ́ Ọwọ́ Tí Ẹ̀sìn Fi Ń Mú Ọ̀rọ̀ OGUN? 5
Ǹjẹ́ O Fara Mọ́ Ọwọ́ Tí Ẹ̀sìn Fi Ń Mú ÌWÀ RERE? 6
Ǹjẹ́ Ẹ̀sìn Kankan Tiẹ̀ Wà Téèyàn Lè GBÁRA LÉ? 7
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀ —Bí Àwọn Tó Tún Ìgbéyàwó Ṣe Ṣe Lè Ṣàṣeyọrí 8
Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ó ‘Ń Mú Inú Wa Dùn’ 11
Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà 12
Ìjíròrò Láàárín Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti Ẹnì Kan—Ǹjẹ́ Ìyà Tó Ń Jẹ Wá Tiẹ̀ Kan Ọlọ́run? 14
KA ÀPILẸ̀KỌ TÓ KÙ LÓRÍ ÌKÀNNÌ | www.jw.org/yo
ÀWỌN ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN Ń BÉÈRÈ NÍPA ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ—Kí Nìdí Tí Ẹ Tún Fi Máa Ń Wàásù Fáwọn Tó Ti Ní Ẹ̀sìn Tiwọn?