Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ 2013
Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Ẹ Máa Bá Ara Yín Sọ̀rọ̀ Kẹ́ Ẹ Lè Túbọ̀ Ṣera Yín Lọ́kan, 5/15
Ẹ Máa Gba Ti Ara Yín Rò Kẹ́ Ẹ sì Máa fún Ara Yín Ní Ìṣírí, 8/15
Ẹ̀yin Olùṣọ́ Àgùntàn, Ẹ Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Ńlá Náà, 11/15
Máa Ṣe Ìpinnu Tó Dára Kó O Má Bàa Pàdánù Ogún Tẹ̀mí Rẹ, 5/15
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
BÍBÉLÌ
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
“Èmi Fúnra Mi Wádìí Láti Mọ Ohun Tí Bíbélì Sọ” (L. Alifonso), 2/1
“Kò Ṣe Mí Mọ́ Bíi Pé Mo Gbọ́dọ̀ Yí Ayé Yìí Pa Dà” (J. Sylgren), 7/1
‘Mo Ronú Gidigidi Nípa Ibi Tí Mo Ń Bọ́rọ̀ Ayé Mi Lọ’ (A. Hancock), 8/1
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
Ní Ísírẹ́lì ìgbàanì, ṣé wọ́n máa ń kan àwọn ọ̀daràn tí wọ́n bá fẹ́ pa mọ́ igi? 5/15
Ǹjẹ́ ó yẹ kí àwọn òbí máa jókòó ti ọmọ wọn tá a yọ lẹ́gbẹ́ láwọn ìpàdé ìjọ? 8/15
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
Bí Àárín Àwọn Tó Tún Ìgbéyàwó Ṣe àti Àwọn Ẹlòmíì Ṣe Lè Tòrò, 5/1
Tọkọtaya Lè Láyọ̀ Kí Wọ́n sì Máa Bá Ara Wọn Gbé Títí Lọ, 9/1
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
A Fi Àádọ́ta Ọdún Ṣe Iṣẹ́ Ìsìn ní Ilẹ̀ Olótùútù (A. àti A. Mattila), 4/15
A Ṣe Tán Láti Sin Jèhófà Níbikíbi Tó Bá Fẹ́ (M. àti J. Hartlief), 7/15
Jèhófà Bù Kún Mi Gan-an Torí Pé Mo Ṣègbọràn Sí I (E. Piccioli), 6/15