Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
January 1, 2014
© 2014 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ǹjẹ́ Ikú Ni Òpin Ìgbésí Ayé Ẹ̀dá?
OJÚ ÌWÉ 3-7
Oró Ikú 3
Aráyé Ń Sapá Kí Wọ́n Lè Ṣẹ́gun Ikú 4
Ikú Kọ́ Ni Òpin Ìgbésí Ayé Ẹ̀dá! 6
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Ìjíròrò Láàárín Ẹlẹ́rìí Jèhófà Àti Ẹnì Kan—Kí Nìdí Tí Ọlọ́run fi Fàyè Gba Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé? 8
Ǹjẹ́ O Mọ̀? 11
Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà 12
Àjíǹde—Ni Ìrètí Tó Wà Fún Àwọn Òkú 14
KA ÀPILẸ̀KỌ TÓ KÙ LÓRÍ ÌKÀNNÌ | www.jw.org/yo
ÀWỌN OHUN MÍÌ TÍ BÍBÉLÌ SỌ—Kí Ni Ọlọ́run Fẹ́ Kí N Fi Ayé Mi Ṣe?
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ)