Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
February 1, 2014
© 2014 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ogun Tó Da Ayé Rú
OJÚ ÌWÉ 3-7
Ẹni Tó Wà Nídìí Ogun àti Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé 5
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà 8
Ǹjẹ́ O Mọ̀? 10
Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé. . . Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Fàyè Gba Ìnilára? 11
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn —Ó Fara Da Ìwà Ìrẹ́jẹ 12
KA ÀPILẸ̀KỌ TÓ KÙ LÓRÍ ÌKÀNNÌ | www.jw.org/yo
ÀWỌN OHUN MÍÌ TÍ BÍBÉLÌ SỌ—Àlàáfíà Ayé—Kí nìdí Tí Ọwọ́ Ò fi Tíì Tẹ̀ ẹ́?
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ)