Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
September 1, 2014
© 2014 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ṣé Àwọn Èèyàn Ò Ní Ba Ayé Yìí Jẹ́ Kọjá Àtúnṣe?
OJÚ ÌWÉ 3-6
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Ǹjẹ́ Òfin Tí Ọlọ́run Fún Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Bá Ẹ̀tọ́ Mu? 7
Ìgbésí Ayé Mi Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Ọlọ́run Mérè Wá 10
Bíbélì Peshitta Lédè Síríákì—Ó Jẹ́ Ká Mọ Àwọn Bíbélì Tí Wọ́n Ṣe Láyé Àtijọ́ 13
KA ÀPILẸ̀KỌ TÓ KÙ LÓRÍ ÌKÀNNÌ | www.jw.org/yo
ÀWỌN OHUN MÍÌ TÍ BÍBÉLÌ SỌ—Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ)