Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
February 2016
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ọ̀SẸ̀ APRIL 4-10, 2016
Ọ̀SẸ̀ APRIL 11-17, 2016
9 Máa Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà
Àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí á jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè mú kí àjọṣe tá a ní pẹ̀lú Jèhófà Ọlọ́run túbọ̀ lágbára. Nínú àpilẹ̀kọ àkọ́kọ́, a máa kẹ́kọ̀ọ́ lára Ábúráhámù. Nínú àpilẹ̀kọ kejì, a máa kẹ́kọ̀ọ́ lára Rúùtù, Hesekáyà àti Màríà, ìyá Jésù.
Ọ̀SẸ̀ APRIL 18-24, 2016
Ọ̀SẸ̀ APRIL 25, 2016–MAY 1, 2016
20 Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ìránṣẹ́ Jèhófà Tó Jẹ́ Adúróṣinṣin
Nínú àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí, a máa jíròrò ohun tí Bíbélì sọ nípa Dáfídì Ọba àtàwọn tó gbé ayé nígbà tó wà láyé. Tá a bá ń ronú nípa àwọn nǹkan tí wọ́n ṣe, àá kọ́ bá a ṣe lè jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà kódà nígbà táwọn nǹkan bá le koko.
26 Ìtàn Ìgbésí Ayé—Jèhófà Ti Jẹ́ Kí N Ṣàṣeyọrí Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Rẹ̀
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
BENIN
Orí òpó ni àwọn ará abúlé Hétin sábà máa ń kọ́ ilé wọn sí. Ọkọ̀ ojú omi kéékèèké ni wọ́n máa ń wọ̀ lọ síbi tí wọ́n bá ń lọ. Ìjọ mẹ́ta ló wà níbẹ̀. Inú àwọn akéde igba ó lé mẹ́ẹ̀ẹ́dógún [215] àtàwọn aṣáájú-ọ̀nà méjìdínlọ́gbọ̀n [28] tó wà láwọn ìjọ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta tó wà lábúlé náà dùn gan an nígbà tí ẹgbẹ̀rún kan ó lé ẹgbẹ̀ta [1,600] èèyàn wá síbi Ìrántí Ikú Kristi tí wọ́n ṣe lọ́dún 2014
IYE ÈÈYÀN
10,703,000
IYE AKÉDE
12,167
IYE ÀWỌN AṢÁÁJÚ-Ọ̀NÀ