Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀
KÍ LÈRÒ RẸ?
Ǹjẹ́ ọ̀rọ̀ tí àwọn èèyàn mọ̀ bí ẹni mowó yìí lè ṣe ẹ́ láǹfààní:
“Ọlọ́run nífẹ̀ẹ́ ayé tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́ tí ó fi fi Ọmọ bíbí rẹ̀ kan ṣoṣo fúnni”?—Jòhánù 3:16.
Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ yìí ṣàlàyé bí ìyà tí Jésù jẹ àti ikú rẹ̀ ṣe lè ṣe ẹ́ láǹfààní.