ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • wp17 No. 3 ojú ìwé 1-2
  • Bí Ọ̀rọ̀ Àwọn Ẹlẹ́ṣin Mẹ́rin Yìí Ṣe Kàn Ọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Bí Ọ̀rọ̀ Àwọn Ẹlẹ́ṣin Mẹ́rin Yìí Ṣe Kàn Ọ́
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2017
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2017
wp17 No. 3 ojú ìwé 1-2
Ìwé Ìròyìn Ilé Ìṣọ́, No. 3, 2017 | Bí Ọ̀rọ̀ Àwọn Ẹlẹ́ṣin Mẹ́rin Yìí Ṣe Kàn Ọ́

Bí Ọ̀rọ̀ Àwọn Ẹlẹ́ṣin Mẹ́rin Yìí Ṣe Kàn Ọ́

No. 3 2017

© 2017 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania

Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.

Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.

Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.

ÌWÉ ÌRÒYÌN Ilé Ìṣọ́ yìí ń gbé Jèhófà Ọlọ́run tó jẹ́ Alákòóso ayé òun ọ̀run ga. Ó ń fi ìhìn rere tu àwọn èèyàn nínú pé, láìpẹ́, Ìjọba Ọlọ́run yóò fòpin sí gbogbo ìwà ibi, á sì sọ ilẹ̀ ayé di Párádísè. Ìwé ìròyìn yìí ń gbani níyànjú láti nígbàgbọ́ nínú Jésù Kristi tó kú ká lè ní ìyè àìnípẹ̀kun. Jésù sì ti ń ṣàkóso báyìí gẹ́gẹ́ bí Ọba Ìjọba Ọlọ́run. Láti ọdún 1879 la ti ń tẹ ìwé ìròyìn yìí déédéé, kì í sì í dá sí ọ̀rọ̀ ìṣèlú. Orí Bíbélì ni gbogbo ohun tó ń sọ dá lé.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́