Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
3 Ìtàn Ìgbésí Ayé—Jèhófà Dá Mi Lọ́lá Bí Mo Tiẹ̀ Jẹ́ Ọmọ Tálákà
9 Àlàáfíà—Báwo Lo Ṣe Lè Ní In?
Ọ̀SẸ̀ JULY 9-15, 2018
12 Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Tó Ń “So Èso Pẹ̀lú Ìfaradà”
Ọ̀SẸ̀ JULY 16-22, 2018
17 Kí Nìdí Tá A Fi Ń “Bá A Nìṣó ní Síso Èso Púpọ̀”?
Àpilẹ̀kọ àkọ́kọ́ ṣàlàyé àpèjúwe tí Jésù ṣe nípa àjàrà àti afúnrúgbìn kan àti ẹ̀kọ́ táwọn àpèjúwe náà kọ́ wa nípa iṣẹ́ ìwàásù. Àpilẹ̀kọ kejì ṣàlàyé àwọn ohun tí Bíbélì sọ tó ń mú ká máa bá iṣẹ́ ìwàásù nìṣó láìṣàárẹ̀.
Ọ̀SẸ̀ JULY 23-29, 2018
22 Mọ Ọ̀tá Rẹ
Ọ̀SẸ̀ JULY 30, 2018–AUGUST 5, 2018
27 Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ Dúró Gbọn-In Lòdì sí Èṣù
Sátánì ni ọ̀tá wa. Báwo ni agbára rẹ̀ ṣe pọ̀ tó? Ibo ni agbára rẹ̀ mọ? Báwo ni gbogbo àwa Kristẹni títí kan àwọn ọ̀dọ́ ṣe lè dojú ìjà kọ ọ́ ká sì borí rẹ̀? Àwọn àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí, á sì jẹ́ ká túbọ̀ dúró lórí ìpinnu wa láti kọjú ìjà sí Èṣù.