Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JANUARY 2019
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: MARCH 4–APRIL 7, 2019
© 2018 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Ọ̀pọ̀ èèyàn ló ń wá sí Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 5, ìpínrọ̀ 1 àti 2)