Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN
Bí Èlíjà ṣe jẹ́ olóòótọ́, tó sì ní ìfaradà lè ràn wá lọ́wọ́ káwa náà lè jẹ́ kí ìgbàgbọ́ wa lágbára sí i lákòókò ìṣòro.
(Lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌGBÀGBỌ́ NÍNÚ ỌLỌ́RUN.)
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Ẹnì kan tó wà nínú ẹgbẹ́ ọ̀daràn tẹ́lẹ̀ gbà pé agbára tí Bíbélì ní láti yí ìgbésí ayé ẹni pa dà ló tún ayé òun ṣe dòní. Ó ti wá sún mọ́ Ọlọ́run gan-an.
(Lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀLÀÁFÍÀ ÀTI AYỌ̀.)