Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN
Jónátánì—“Kò Sí Ìdílọ́wọ́ fún Jèhófà”
Jónátánì mú ẹnì kan ṣoṣo dání lọ gbéjà ko àwọn ọmọ ogun Filísínì tó dìhámọ́ra níbi tí wọ́n pabùdó sí, mánigbàgbé lohun tó sì tẹ̀yìn ẹ̀ yọ.
(Lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌGBÀGBỌ́ NÍNÚ ỌLỌ́RUN.)
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Nígbà tí Renée pé ọmọ ọdún mẹ́rìnlá (14), ó kúrò nílé torí ìwà bàbá rẹ̀. Kí ló mú káwọn méjèèjì pa dà rẹ́ nígbà tó yá?
(Lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀLÀÁFÍÀ ÀTI AYỌ̀.)