Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ ÌRÒYÌN YÌÍ
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 18: July 1-7, 2019
2 Ìfẹ́ àti Ìdájọ́ Òdodo Nínú Ìjọ Kristẹni
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 19: July 8-14, 2019
8 Máa Fi Ìfẹ́ Hàn sí Àwọn Tí Wọ́n Hùwà Ìkà Sí, Kó O sì Máa Ṣèdájọ́ Òdodo
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 20: July 15-21, 2019
14 Bá A Ṣe Lè Pèsè Ìtùnú fún Àwọn Tí Wọ́n Bá Lò Pọ̀ Nígbà Tí Wọ́n Wà Lọ́mọdé
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 21: July 22-28, 2019
21 Má Ṣe Jẹ́ Kí “Ọgbọ́n Ayé Yìí” Nípa Lórí Rẹ