ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w19 July ojú ìwé 32
  • Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
w19 July ojú ìwé 32

Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Apá Àràmàǹdà Tí Octopus Ní

Apá tó rọ̀ tí Octopus ní ti jẹ́ káwọn ẹnjiníà tó ń ṣe rọ́bọ́ọ̀tì ṣe àwọn irinṣẹ́ kan. Àwọn irinṣẹ́ yìí ló máa ń jẹ́ káwọn dókítà ráyè ṣiṣẹ́ abẹ láwọn ibi kọ́lọ́fín ara láìsí pé wọ́n ń fi abẹ la aláìsàn nílàkulà.

Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌMỌ̀ SÁYẸ́ǸSÌ ÀTI BÍBÉLÌ > TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

“Mò Ń Fi Ẹ̀mí Ara Mi Tàfàlà”

Ó dá Óscar lójú pé òun ò bá ti kú tí kì í bá ṣe ti Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tó yí òun pa dà. Kí ló mú kí ẹnì kan tó wá láti El Salvador, tó sì jẹ́ ọmọ ìta tẹ́lẹ̀ yí ìgbésí ayé rẹ̀ pa dà?

Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀLÀÁFÍÀ ÀTI AYỌ̀ > BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́