Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ṣọ́ Àkókò Lò?
Ohun márùn-ún tí kò ní jẹ́ kó ó máa fi àkókò ẹ ṣòfò.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > Ọ̀DỌ́ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ.
TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
Bí Barnacle Ṣe Ń Lẹ̀ Mọ́ Nǹkan
Agbára tí barnacle fi ń lẹ̀ mọ́ nǹkan ju ti gọ́ọ̀mù èyíkéyìí téèyàn ṣe lọ. Ẹnu àìpẹ́ yìí làwọn èèyàn mọ àṣírí bí barnacle ṣe ń lẹ̀ mọ́ nǹkan tó bá lómi lára.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌMỌ̀ SÁYẸ́ǸSÌ ÀTI BÍBÉLÌ > TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?