Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn August
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 231 136.9 13.2 60.6 10.6
Aṣá. Dééd. 17,299 71.0 6.7 26.5 5.7
Aṣá. Olù. 9,281 40.9 6.5 14.3 2.7
Akéde 164,628 10.9 1.0 2.7 0.9
ÀRÒPỌ̀ 191,439 Àwọn Tí A Batisí: 402
A ní ìdí púpọ̀ láti dunnú sí góńgó àgbàyanu tuntun mìíràn tí a ní nínú akéde ní August. A ní 191,439. Àwọn aṣáájú ọ̀nà pé 17,299, a sì batisí àròpọ̀ 11,302, nínú ọdún iṣẹ́ ìsìn náà. A ní ìjọ 3,583 nísinsìnyí ní Nigeria.