Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn February
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 428 135.4 11.5 58.5 9.6
Aṣá. Dééd. 18,002 69.1 6.1 25.5 5.6
Aṣá. Olù. 7,495 42.8 4.2 12.9 2.7
Akéde 168,049 10.9 0.9 3.6 0.9
ÀRÒPỌ̀ 193,974 Àwọn Tí A Batisí: 153
Ìròyin February fi góńgó tuntun mìíràn nínú akéde hàn, tí ó jẹ́ 193,974. Pẹ̀lúpẹ̀lù, iye àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé, tí ó jẹ́ 18,002, jẹ́ góńgó tuntun, èyí sì ni ìgbà àkọ́kọ́ tí a dé orí 18,000. A ní 3,667 ìjọ ní Nàìjíríà nísinsìnyí.