ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 7/96 ojú ìwé 7
  • Àwọn Ìfilọ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ìfilọ̀
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1996
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1996
km 7/96 ojú ìwé 7

Àwọn Ìfilọ̀

◼ Àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a óò fi lọni ní July àti August: A lè fi èyíkéyìí nínú àwọn ìwé pẹlẹbẹ olójú ewé 32 tí ó tẹ̀ lè é yìí lọni fún ọrẹ ₦25: Akoso Naa Ti Yoo Mu Paradise Wá, Ẹmi Awọn Oku—Wọn Ha Le Ran Ọ Lọwọ Tabi Pa Ọ Lara Bi? Wọn Ha Wa Niti Gidi Bi?, Gbádùn Iwalaaye lori Ilẹ Ayé Titilae!, Iwọ Ha Nilati Gbàgbọ́ Ninu Mẹtalọkan Bí?, Ki Ni Ète Igbesi-Aye? Bawo Ni Iwọ Ṣe Le Rí I?, Nígbà Tí Ẹnìkan Tí Ìwọ Fẹ́ràn Bá Kú, Ọlọrun Ha Bikita Nipa Wa Niti Gidi Bi?, àti “Sawo O! Emi Nsọ Ohun Gbogbo Di Ọtun.” Níbi tí ó bá ti yẹ, a lè fi àwọn ìwé pẹlẹbẹ bíi, Our Problems—Who Will Help Us Solve Them? àti Will There Ever Be a World Without War? lọni. September: Efik àti Hausa—Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye, True Peace and Security—How Can You Find It? Gẹ̀ẹ́sì—Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye, Lilaaja Sinu Ilẹ-ayé Titun, The Bible—God’s Word or Man’s? Igbo—Igba Ewe rẹ—Bi o ṣe le Gbadun rẹ Julọ, Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye, True Peace and Security—How Can You Find It?, Yiyan Ọna Igbesi Ayé Ti O Dara Julọ. Yorùbá—Ayọ̀—Bi A Ṣe Lè Rí I, Igba Ewe rẹ—Bi o ṣe le Gbadun rẹ Julọ, Igbesi Aye Yii Ha Ni Gbogbo Ohun Ti O Wà Bi?, Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye. October: Àsansílẹ̀ owó fún Ilé-Ìṣọ́nà tàbí Jí! tàbí fún ìwé ìròyìn méjèèjì. ÀKÍYÈSÍ: Àwọn ìjọ tí yóò nílò àwọn ìwé ìgbétáásì tí a mẹ́nu kàn lókè yìí ní láti béèrè fún wọn lórí Literature Order Form (S-14) olóṣooṣù wọn, ti oṣù tí ń bọ̀.

◼ Bẹ̀rẹ̀ láti September, ọ̀rọ̀ àsọyé fún gbogbo ènìyàn tí àwọn alábòójútó àyíká yóò máa sọ yóò jẹ́ “Ta Ni Ó Dà Bíi Jèhófà Ọlọ́run Wa?”

◼ A ń fi ẹ̀dà méjì Report on Literacy ránṣẹ́ sí ìjọ kọ̀ọ̀kan. Ẹ ní láti kọ ọ̀rọ̀ kún fọ́ọ̀mù yìí ní August 1, kí ẹ sì fi ránṣẹ́ sí wa ní August 6. Ẹ tọ́jú ẹ̀dà kan sínú fáìlì yín. Ẹ ní láti kọ ọ̀rọ̀ kún inú fọ́ọ̀mù náà, yálà ẹ ní kíláàsì mọ̀ọ́kọ-mọ̀ọ́kà tàbí ẹ kò ní.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́