Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn June
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 547 137.6 9.6 59.7 10.1
Aṣá. Dééd. 18,709 69.5 5.8 26.4 5.8
Aṣá. Olù. 4,808 56.0 4.2 17.5 3.8
Akéde 173,590 10.7 0.7 3.6 1.0
ÀRÒPỌ̀ 197,654 Àwọn Tí A Batisí: 960
Ìròyìn iṣẹ́ ìsìn pápá fún June tayọ ní tòótọ́. A ní àwọn góńgó tuntun ti 197,654 akéde àti 18,709 aṣáájú ọ̀nà déédéé. Àwọn ìjọ 3,727 ni a ti fi orúkọ wọn sílẹ̀ nísinsìnyí.