Àwọn Ìfilọ̀
◼ Àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a óò fi lọni ní May: Gbogbo èdè—àsansílẹ̀ owó fún Ilé Ìṣọ́. Àwọn ìwé ìròyìn ẹlẹ́ẹ̀mejì lóṣù fún ọdún kan, ₦280. Ẹlẹ́ẹ̀kan lóṣù fún ọdún kan tàbí ẹlẹ́ẹ̀mejì lóṣù fún oṣù mẹ́fà, ₦140. Fún iṣẹ́ ìsìn àárín ọ̀sẹ̀ àti ní àwọn ìpínlẹ̀ tí a sábà máa ń kárí, a lè lo ìwé pẹlẹbẹ tuntun náà, Kí Ni Ọlọrun Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa? June: Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun. Pọkàn pọ̀ sórí bíbẹ̀rẹ̀ àwọn ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì inú ilé. July àti August: A lè lo èyíkéyìí nínú àwọn ìwé pẹlẹbẹ olójú ewé 32 tí ó tẹ̀ lé e yìí: Akoso Naa Ti Yoo Mu Paradise Wá, Gbádùn Iwalaaye lori Ilẹ Ayé Titilae!, Iwọ Ha Nilati Gbàgbọ́ Ninu Mẹtalọkan Bí?, Ki Ni Ète Igbesi-Aye? Bawo Ni Iwọ Ṣe Le Rí I?, Nígbà Tí Ẹnìkan Tí Ìwọ Fẹ́ràn Bá Kú, Ọlọrun Ha Bikita Nipa Wa Niti Gidi Bi? ÀKÍYÈSÍ: Kí àwọn ìjọ tí yóò bá nílò àwọn ìwé ìgbétásì tí a mẹ́nu kàn lókè yí béèrè fún wọn lórí Literature Order Form (S-14) olóṣooṣù wọn ti oṣù tí ń bọ̀.
◼ Nígbà tí ìjọ tàbí ẹnì kọ̀ọ̀kan bá kọ lẹ́tà sí Society, ẹ gbọ́dọ̀ kọ nọ́ńbà àyíká tí ìjọ náà wà sínú àdírẹ́sì yín, kí ó wà lára àpò ìwé àti nínú àdírẹ́sì tí ń bẹ nínú lẹ́tà.
◼ Títúmọ̀ sí èdè àwọn adití yóò wà ní àwọn àpéjọ àyíká tí ó tẹ̀ lé e wọ̀nyí: EE-4 (Igwuruta Ali), June 7-8, 1997; EE-8 (Akabo), October 4-5, 1997; EE-9 (Ùlì), September 13-14, 1997; àti WE-13 (Ọ̀tà), August 16-17, 1997.
◼ Alábòójútó olùṣalága yóò ṣàyẹ̀wò láti rí sí i pé a ṣe àwọn àtúnṣe tí ó tẹ̀ lé e yìí sórí àwọn ẹ̀dà Cost List ti March 1, 1997, tí ó jẹ́ ti ìjọ: Ike Káàdì Àyà/ike káàdì Ìpínlẹ̀, ₦10 ẹyọ kan; Ìkésíni Ìpàdé, ₦90 fún 500 ẹ̀dà.
◼ Àwọn Ìtẹ̀jáde Tí Ó Wà Lọ́wọ́ Nísinsìnyí:
Àṣírí Ayọ̀ Ìdílé —Ẹ́fíìkì, Gẹ̀ẹ́sì, Ègùn, Haúsá, Ìgbò, Ísókó, Tiv, Yorùbá
Kí Ni Ọlọrun Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?—Ẹ́fíìkì, Gẹ̀ẹ́sì, Haúsá, Ìgalà, Ìgbò, Ísókó, Tiv, Yorùbá
Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun—Ègùn
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti Ìmọ̀ Ẹ̀kọ́—Ẹ́fíìkì, Ìgbò, Yorùbá
Ọlọrun Ha Bikita Nipa Wa Niti Gidi Bi?—Tiv
Àìléwu Kárí-Ayé Labẹ “Ọmọ-Aládé Alaafia”—Ìgbò
◼ Àwọn Ìtẹ̀jáde Tuntun Tí Ó Wà Lọ́wọ́:
Ọlọrun Ha Bikita Nipa Wa Niti Gidi Bi?—Ìgalà
Bí A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Awọn Ìjíròrò Bibeli Kí A Sì Máa Báa Nìṣó—Ẹ́fíìkì, Haúsá, Ìgbò, Ísókó, Tiv, Yorùbá
Ki Ni Ète Igbesi-Aye? Bawo Ni Iwọ Ṣe Le Rí I?—Ìgalà
Iwe Itan Bibeli Mi—Tiv
Igbesi-aye ninu Aye Titun alalaafia kan (Ìwé Àṣàrò Kúkúrú No. 15)—Èdè Àwọn Adití
◼ Àwọn Compact Disc Tuntun Tí Ó Wà Lọ́wọ́:
Kingdom Melodies, Àkójọ 1 (cdm-1)
◼ Àwọn Kásẹ́ẹ̀tì Àtẹ́tísí Tuntun Tí Ó Wà Lọ́wọ́:
Kí Ni Ọlọrun Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?—Gẹ̀ẹ́sì
Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun—Gẹ̀ẹ́sì
◼ Àwọn Kásẹ́ẹ̀tì Fídíò Tuntun Tí Ó Wà Lọ́wọ́:
Kí Ni Ọlọrun Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?—Èdè Àwọn Adití
Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun (Apá 2 títí dé 6)—Èdè Àwọn Adití