Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ìwé Ìjọ
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ ìjọ nínú ìwé Ọkunrin Titobilọla Julọ Ti O Tii Gbé Ayé Rí.
June 2: Orí 103 sí 105
June 9: Orí 106 àti 107
June 16: Orí 108 sí 110
June 23: Orí 111 sí ìsọ̀rí orí ọ̀rọ̀ “Awọn Wundia Ọlọ́gbọ́n ati Òmùgọ̀”
June 30: Orí 111 láti ìsọ̀rí orí ọ̀rọ̀ “Awọn Wundia Ọlọ́gbọ́n ati Òmùgọ̀” dé ìparí orí náà