Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn March
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 402 132.7 12.4 59.7 11.1
Aṣá. Déédé 20,361 65.4 6.5 24.2 5.5
Aṣá. Olù. 5,546 55.0 4.3 16.2 3.6
Akéde 180,276 10.3 0.8 3.6 1.0
ÀRÒPỌ̀ 206,585 Àwọn Tí A Batisí: 728
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a kò ní góńgó tuntun nínú iye àwọn akéde ní oṣù March, èyí ni oṣù kẹta tẹ̀ léra tí a ti rí iye tí ó ju 206,000 tí wọ́n ròyìn. A dé góńgó tuntun nínú iye àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé, tí àwọn 20,361 ròyìn. Nísinsìnyí, a ti forúkọ 4,007 ìjọ sílẹ̀.