Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn August
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 492 136.0 13.5 62.2 11.0
Aṣá. Déédé 21,493 69.7 7.0 25.6 5.7
Aṣá. Olù. 13,257 57.7 3.9 16.0 3.4
Akéde 187,064 11.2 0.9 3.7 1.0
ÀRÒPỌ̀ 222,306 Àwọn Tí A Batisí: 824
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa ti oṣù August gbé góńgó 215,000 akéde kalẹ̀ fún oṣù August. Inú wa dùn jọjọ láti kọjá iye yìí, tí a sì ní góńgó tí ó ju ti ìgbàkígbà rí lọ ti 222,306 akéde tí ó ròyìn ní oṣù August. Èyí ni ìgbà àkọ́kọ́ tí a kọjá góńgó 220,000. Àwọn 21,493 aṣáájú ọ̀nà déédéé jẹ́ góńgó tuntun pẹ̀lú. A kún fún ìmoore sí Jèhófà nítorí bí ó ṣe ń bù kún iṣẹ́ wa.