Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn April
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 469 132.8 11.7 57.7 10.5
Aṣá. Déédéé 22,046 59.2 7.0 22.1 5.3
Aṣá. Olù. 15,149 47.9 4.3 13.8 3.3
Akéde 179,698 10.2 0.9 3.3 0.9
ÀRÒPỌ̀ 217,362 Àwọn Tí A Batisí: 1,150
A ní góńgó tuntun ti 22,046 aṣáájú ọ̀nà déédéé. Èyí fi ìpín 15.9 nínú ọgọ́rùn-ún ju ìpíndọ́gba ti ọdún tó kọjá lọ, èyí tó jẹ́ 19,020 aṣáájú ọ̀nà déédéé.