Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn November
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 479 133.7 13.5 61.6 11.4
Aṣá. Déédéé 24,103 55.6 7.3 21.3 5.4
Aṣá. Olù. 6,175 47.7 5.0 14.8 3.7
Akéde 191,018 10.1 1.0 3.5 1.0
ÀRÒPỌ̀ 221,775 Àwọn Tí A Batisí: 5,651
Iye àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé pọ̀ ju ti ìgbàkígbà rí lọ lóṣù yìí o! Àròpọ̀ iye àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé tí wọ́n jẹ́ 24,103 tí wọ́n ròyìn fi ọgọ́fà ó dín mẹ́rin pọ̀ ju iye àwọn táa ní lóṣù September 1999, tí wọ́n jẹ́ 23,987.