Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn January
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 459 129.5 15.3 59.9 11.2
Aṣá. Déédéé 24,773 57.0 7.9 21.5 5.3
Aṣá. Olù. 7,829 48.2 4.8 14.0 3.4
Akéde 194,463 10.7 1.2 3.6 1.0
ÀRÒPỌ̀ 227,524 Àwọn Tí A Batisí: 263
A láyọ̀ láti ròyìn pé iye àwọn akéde tún pọ̀ sí i ní oṣù January ju ti ìgbàkigbà rí lọ, wọ́n jẹ́ 227,524. Àròpọ̀ iye àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé pẹ̀lú, tó jẹ́ 24,773, pọ̀ ju ti tẹ́lẹ̀ lọ.