ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 7/01 ojú ìwé 2-3
  • Àwọn Ìfilọ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ìfilọ̀
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2001
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2001
km 7/01 ojú ìwé 2-3

Àwọn Ìfilọ̀

◼ Ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a ó fi lọni ní oṣù July: A lè lo èyíkéyìí nínú àwọn ìwé pẹlẹbẹ olójú ewé méjìlélọ́gbọ̀n tó tẹ̀ lé e yìí: Akoso Naa Ti Yoo Mu Paradise Wá, Gbádùn Iwalaaye lori Ilẹ Ayé Titilae!, Iwọ Ha Nilati Gbàgbọ́ Ninu Mẹtalọkan Bí?, Ìwọ Lè Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run!, Ki Ni Ète Igbesi-Aye? Báwo Ni Iwọ Ṣe Le Rí I?, Kí Ní Ń Ṣẹlẹ̀ sí Wa Nígbà tí A Bá Kú?, Nígbà Tí Ẹnìkan Tí Ìwọ Fẹ́ràn Bá Kú, Orukọ Atọrunwa naa Tí Yoo Wà Titilae, Ọlọrun Ha Bikita Nipa Wa Niti Gidi Bi? àti “Sawo O! Emi Nsọ Ohun Gbogbo Di Ọtun.” Àwọn ìwé pẹlẹbẹ náà, Ẹmi Awọn Oku—Wọn Ha Le Ran Ọ Lọwọ Tabi Pa Ọ Lara Bi? Wọn Ha Wa Niti Gidi Bi?, àti Ìwé Kan Tí Ó Wà fún Gbogbo Ènìyàn ni a lè fi lọni tó bá yẹ. August àti September: Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye. (Bí èyí kò bá sí, a lè fi ìwé olójú ewé 192 èyíkéyìí tọ́jọ́ rẹ̀ ti pẹ́ lọni.) October: Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ àti Jí! Níbi tí wọ́n bá ti fi ìfẹ́ hàn nígbà ìpadàbẹ̀wò, a lè fi ìforúkọsílẹ̀ fún ìwé ìròyìn lọni.

◼ Bẹ̀rẹ̀ láti oṣù September, àwọn alábòójútó àyíká yóò máa sọ àsọyé fún gbogbo èèyàn tí àkọlé rẹ̀ jẹ́, “Bí Àwọn Kristẹni Tòótọ́ Ṣe Ń Ṣe Ẹ̀kọ́ Ọlọ́run Lọ́ṣọ̀ọ́.”

◼ A fẹ́ ṣe àlàyé kúlẹ̀kúlẹ̀ nípa àwọn àpéjọ àgbègbè táa pè ní North 1 títí dé North 4 nínú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa ti May 2001. Àwọn ìlú tó wà nísàlẹ̀ yìí ni ibi tí a ó ti ṣe àpéjọ àgbègbè lọ́dún yìí, orúkọ àwọn àyíká tí yóò lọ síbẹ̀ sì wà níbẹ̀ pẹ̀lú.

October 26-28, 2001

ZARIA 1 (Yorùbá) Y-13B

November 2-4, 2001

SULEJA 1 (Gẹ̀ẹ́sì) NE-5: A sí F; NE-7: K sí Z; NE-1A: Yelwa-Yauri

ZARIA 2 (Gẹ̀ẹ́sì) NE-1A: Gbogbo ìjọ àyàfi Yelwa-Yauri; NE-1B: A sí M; NE-2: K sí Z

November 9-11, 2001

SULEJA 2 (Gẹ̀ẹ́sì) NE-5: G sí Z; NE-7: A sí J

ZARIA 3 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Amẹ́ríkà) NE-1B: N sí Z; NE-2: A sí J

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́