Àwọn Ìfilọ̀
◼ Ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a ó fi lọni ní oṣù December: Ọkunrin Titobilọla Julọ Ti O Tii Gbé Ayé Rí. O lè fi Iwe Itan Bibeli Mi tàbí Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye lọni bí àfidípò. January: Ìwé olójú ewé 192 èyíkéyìí tí ìjọ bá ní, tí a tẹ̀ jáde ṣáájú ọdún 1987. February: Ìṣípayá—Òtéńté Rẹ̀ Títóbilọ́lá Kù Sí Dẹ̀dẹ̀!, tàbí ìwé olójú ewé 192 mìíràn tí ọjọ́ rẹ̀ ti pẹ́ ju èyí tá a dárúkọ yìí tí ìjọ bá ní lọ́wọ́. March: Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun. A ó sapá lákànṣe láti bẹ̀rẹ̀ àwọn ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì inú ilé.
◼ Àwọn Ìtẹ̀jáde Tuntun Tó Wà:
Ìdìpọ̀ Ilé Ìṣọ́ ọdún 2000—Gẹ̀ẹ́sì
Ìdìpọ̀ Jí! ọdún 2000—Gẹ̀ẹ́sì
Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà—Ìmọ́lẹ̀ fún Gbogbo Aráyé, Apá Kìíní—Onílẹ́tà Gàdàgbà—Gẹ̀ẹ́sì
Is There a Creator Who Cares About You?—Ìwé Àwọn Afọ́jú
2001 Yearbook of Jehovah’s Witnesses—Ìwé Àwọn Afọ́jú
◼ Fídíò Tuntun Tó Wà:
Warning Examples for Our Day (PAL)—Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Amẹ́ríkà