Àwọn Ibi Tí a ó Ti Ṣe Àpéjọ Àgbègbè Ọdún 2004
Bẹ̀rẹ̀ láti àpéjọ àgbègbè ọdún 2004, a ò ní máa tẹ orúkọ àwọn ìjọ tó máa lọ sí àpéjọ kọ̀ọ̀kan jákèjádò orílẹ̀-èdè yìí jáde. Ìjọ kọ̀ọ̀kan yóò gba lẹ́tà tá a fi sọ àpéjọ àgbègbè tí a yàn wọ́n sí. Bó o bá fẹ́ mọ ìjọ tí a yan àwọn ọ̀rẹ́ àti mọ̀lẹ́bí rẹ sí, jọ̀wọ́ kọ̀wé sí wọn láti ṣèwádìí, má ṣe kọ̀wé sí ẹ̀ka ọ́fíìsì.
October 8-10, 2004
AGBOR 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
Ọ̀TÀ 1 (Yorùbá)
ÙBOGÒ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
October 15-17, 2004
AGBOR 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
Ọ̀TÀ 2 (Yorùbá)
ÙBOGÒ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙLÌ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
October 22-24, 2004
AGBOR 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
DÁLÙWỌ́N 1 (Yorùbá)
IGWURUTA ALI 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
JOS 1 (Haúsá)
MGBOKO UMUORIA 3 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙLÌ 2 (Ìgbò)
UYÓ 1 (Ẹ́fíìkì)
October 29-31, 2004
AGBOR 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
CALABAR 1 (Ẹ́fíìkì)
DÁLÙWỌ́N 2 (Yorùbá)
IGWURUTA ALI 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
JOS 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 4 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 4 (Yorùbá)
ÙBOGÒ 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙLÌ 3 (Ìgbò)
UYÓ 2 (Ẹ́fíìkì)
November 5-7, 2004
AGBOR 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
CALABAR 2 (Ẹ́fíìkì)
DÁLÙWỌ́N 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
ẸNÚGU 1 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 1 (Yorùbá)
IGWURUTA ALI 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT AKAN 1 (Ẹ́fíìkì)
IKOT EKPENE 1 (Ẹ́fíìkì)
JOS 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 5 (Ìgbò)
ÒKÌTÌPUPA 1 (Yorùbá)
Ọ̀TÀ 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
SÚLÈJA 1 (Yorùbá)
ÙBOGÒ 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙLÌ 4 (Ìgbò)
UYÓ 3 (Ẹ́fíìkì)
ZARIA 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
November 12-14, 2004
AGBOR 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÀKÚRẸ́ 1 (Yorùbá)
CALABAR 3 (Ẹ́fíìkì)
DÁLÙWỌ́N 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
ẸNÚGU 2 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT AKAN 2 (Ẹ́fíìkì)
IKOT EKPENE 2 (Ẹ́fíìkì)
KATSINA ALA 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 6 (Ìgbò)
ÒKÌTÌPUPA 2 (Yorùbá)
Ọ̀TÀ 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
SÚLÈJA 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 6 (Ísókó)
ÙLÌ 5 (Ìgbò)
UYÓ 4 (Ẹ́fíìkì)
ZARIA 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
November 19-21, 2004
AGBOR 7 (Ìgbò)
ÀKÚRẸ́ 2 (Yorùbá)
BENIN CITY 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
CALABAR 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
DÁLÙWỌ́N 5 (Yorùbá)
ẸNÚGU 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÌBÀDÀN 3 (Yorùbá)
IGWURUTA ALI 6 (Ìgbò)
IKOT EKPENE 3 (Ẹ́fíìkì)
ÌLỌRIN 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
KATSINA ALA 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 7 (Ìgbò)
ÒKÌTÌPUPA 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
Ọ̀TÀ 7 (Gẹ̀ẹ́sì)
SÚLÈJA 3 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Amẹ́ríkà)
ÙBOGÒ 7 (Ísókó)
ÙLÌ 6 (Ìgbò)
UYÓ 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
November 26-28, 2004
AGBOR 8 (Esan)
ÀKÚRẸ́ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
BENIN CITY 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
CALABAR 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
DÁLÙWỌ́N 6 (Yorùbá)
ẸNÚGU 4 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 4 (Yorùbá)
IGWURUTA ALI 7 (Ìgbò)
IKOT EKPENE 4 (Ẹ́fíìkì)
ILÉṢÀ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÌLỌRIN 2 (Yorùbá)
KATSINA ALA 3 (Tífí)
MGBOKO UMUORIA 8 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 8 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 8 (Ùròbò)
ÙLÌ 7 (Ìgbò)
UYÓ 6 (Ẹ́fíìkì)
December 3-5, 2004
ÀKÚRẸ́ 4 (Yorùbá)
BENIN CITY 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
CALABAR 6 (Ẹ́fíìkì)
DÁLÙWỌ́N 7 (Yorùbá)
ẸNÚGU 5 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 8 (Kánà)
IKOT EKPENE 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
ILÉṢÀ 2 (Yorùbá)
MGBOKO UMUORIA 9 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 9 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Amẹ́ríkà)
ÙBOGÒ 9 (Ùròbò)
ÙLÌ 8 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Amẹ́ríkà)
UYÓ 7 (Ẹ́fíìkì)
December 10-12, 2004
BENIN CITY 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
CALABAR 7 (Gẹ̀ẹ́sì)
DÁLÙWỌ́N 8 (Gẹ̀ẹ́sì)
ẸNÚGU 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 9 (Gòkánà)
IKOT EKPENE 6 (Ẹ́fíìkì)
ILÉṢÀ 3 (Yorùbá)
MGBOKO UMUORIA 10 (Ìgbò)
ÙBOGÒ 10 (Ùròbò)
UYÓ 8 (Ẹ́fíìkì)
December 17-19, 2004
BADAGRY (Ègùn)
BENIN CITY 5 (Ẹ̀dó)
CALABAR 8 (Gẹ̀ẹ́sì)
DÁLÙWỌ́N 9 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 10 (Abua)
ILÉṢÀ 4 (Yorùbá)
MGBOKO UMUORIA 11 (Ìgbò)
ÙBOGÒ 11 (Ijaw)
UYÓ 9 (Ẹ́fíìkì)
January 7-9, 2005
DÁLÙWỌ́N 10 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTAL ALI 11 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Amẹ́ríkà)
MGBOKO UMUORIA 12 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 10 (Yorùbá)
ÙBOGÒ 12 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Amẹ́ríkà)
UYÓ 10 (Gẹ̀ẹ́sì)
January 14-16, 2005
IGWURUTAL ALI 12 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 13 (Gẹ̀ẹ́sì)
Ọ̀TÀ 11 (Gẹ̀ẹ́sì)
UYÓ 11 (Gẹ̀ẹ́sì)