ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 5/05 ojú ìwé 2-7
  • Àwọn Ìfilọ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ìfilọ̀
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2005
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2005
km 5/05 ojú ìwé 2-7

Àwọn Ìfilọ̀

◼ Ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tá a ó lò lóṣù May: Ẹ lo ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ àti Jí! Nígbà tẹ́ ẹ bá padà lọ sọ́dọ̀ àwọn tó fìfẹ́ hàn, tó fi mọ́ àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi tàbí àwọn ìpàdé ìjọ mìíràn, ṣùgbọ́n tí wọn ò tíì máa wá sáwọn ìpàdé ìjọ déédéé, ìwé Jọ́sìn Ọlọ́run Tòótọ́ Kan Ṣoṣo Náà ni kí ẹ máa fún wọn. Ẹ sapá ní gbogbo ọ̀nà kẹ́ ẹ lè bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ wọn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, pàápàá báwọn kan bá ti ka ìwé Ìmọ̀ àti ìwé pẹlẹbẹ Béèrè tẹ́lẹ̀. June: Ìwé Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Olùkọ́ Ńlá Náà ni kẹ́ ẹ lò, báwọn kan bá sì sọ pé àwọn kì í ṣe òbí, ẹ fún wọn ní ìwé pẹlẹbẹ Béèrè. Ẹ gbìyànjú láti bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. July àti August: Èyíkéyìí nínú àwọn ìwé pẹlẹbẹ olójú ìwé 32 yìí ni kẹ́ ẹ lò: Akoso Naa Ti Yoo Mu Paradise Wá, Ẹmi Awọn Oku—Wọn Ha Le Ran Ọ Lọwọ Tabi Pa Ọ Lara Bi? Wọn Ha Wa Niti Gidi Bi?, Gbádùn Iwalaaye lori Ilẹ Ayé Titilae!, Ìwé Kan Tí Ó Wà fún Gbogbo Ènìyàn, Iwọ Ha Nilati Gbàgbọ́ Ninu Mẹtalọkan Bí? Ki Ni Ète Igbesi-Aye? Bawo Ni Ìwọ Ṣe Le Rí I?, Kí Ní Ń Ṣẹlẹ̀ sí Wa Nígbà Tí A Bá Kú?, Nígbà Tí Ẹnìkan Tí Ìwọ Fẹ́ràn Bá Kú, Orukọ Atọrunwa naa Tí Yoo Wà Titilae, Ọlọ́run Ha Bikita Nipa Wa Niti Gidi Bi?, Ọ̀nà Tó Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun—Ṣé O Ti Rí I?, “Sawo O! Emi Nsọ Ohun Gbogbo Di Ọtun.”

◼ Ẹ jọ̀wọ́, á fẹ́ fi tó yín létí pé ìwé ìròyìn Jí! ò ní máa jáde lédè Twi mọ́. Nítorí èyí, kò ní máa sí nínú ẹrù tá a ó máa kó ránṣẹ́ mọ́. Ìdí ni pé ẹ̀dà ti April sí June 2005 la máa tẹ̀ jáde gbẹ̀yìn lédè yìí.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́