Àwọn Kókó Inú Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn
Inú wa dùn láti sọ fún yín pé, ní ọdún 2009, àádóje dín méjì [128] àwọn ìjọ tuntun àti àwùjọ mọ́kànlélógún [21] tó wà ní àdádó la dá sílẹ̀ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Èyí jẹ́ ẹ̀rí pé Jèhófà ń bù kún iṣẹ́ kíkó àwọn tó nífẹ̀ẹ́ sí òtítọ́ jọ lórílẹ̀ èdè yìí.—Mát. 9:37, 38.