Àwọn Ìfilọ̀
◼ Ìwé tá a máa lò ní February: Ẹ lo èyíkéyìí lára àwọn ìwé pẹlẹbẹ olójú ewé méjìlélọ́gbọ̀n yìí: Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run!, Tẹ́tí sí Ọlọ́run tàbí Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé. March àti April: Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ àti Jí! May: Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? Ṣé Wàá Fẹ́ Mọ Òtítọ́?
◼ Ẹṣin ọ̀rọ̀ àkànṣe àsọyé fún gbogbo ènìyàn ní àkókò Ìrántí Ikú Kristi lọ́dún 2015 ni “Ọlọ́run Ṣèlérí Pé Ìdílé Máa Láyọ̀ Títí Láé.”