ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 July ojú ìwé 4
  • July 11 Sí 17

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • July 11 Sí 17
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 July ojú ìwé 4

July 11 Sí 17

SÁÀMÙ 69-73

  • Orin 92 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Àwọn Èèyàn Jèhófà Jẹ́ Onítara fún Ìjọsìn Tòótọ́”: (10 min.)

    • Sm 69:9—Ó yẹ kí àwọn èèyàn mọ̀ pé lóòótọ́ la jẹ́ onítara fún ìjọsìn tòótọ́ (w10 12/15 ojú ìwé 7 sí 11 ìpínrọ̀ 2 sí 17)

    • Sm 71:17, 18—Àwọn àgbàlagbà lè ran àwọn ọ̀dọ́ lọ́wọ́ kí wọ́n lè jẹ́ onítara (w14 1/15 ojú ìwé 23 sí 25 ìpínrọ̀ 4 sí 10)

    • Sm 72:3, 12, 14, 16-19—Ìtara ló ń jẹ́ ká sọ fún àwọn èèyàn nípa nǹkan tí Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe fún aráyé (w15 10/1 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 3; w10 8/15 ojú ìwé 32 ìpínrọ̀ 19 àti 20)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sm 69:4, 21—Àwọn àsọtẹ́lẹ̀ wo ni àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí sọ tó ṣẹ sí Mèsáyà lára? (w11 8/15 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 17; w11 8/15 ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 15)

    • Sm 73:24—Báwo ni Jèhófà ṣe ń dá àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ lọ́lá tàbí mú kí wọ́n wọnú ògo? (w13 2/15 ojú ìwé 25 àti 26 ìpínrọ̀ 3 àti 4)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 73:1-28

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn wp16.4—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn wp16.4

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 5 ìpínrọ̀ 3 àti 4

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 140

  • “Ṣé O Lè Gbìyànjú Rẹ̀ Wò fún Ọdún Kan?”: (15 min.) Ní ṣókí, ẹ jíròrò àpilẹ̀kọ náà àti “Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Iṣẹ́ Ìsìn Aṣáájú-Ọ̀nà Déédéé.” Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Mo Yan Ọ̀nà Ìgbésí Ayé Tó Máa Wà Pẹ́ Títí. Kí ẹ sì jíròrò rẹ̀. Ó wà lórí Ètò Tẹlifíṣọ̀n JW (Lọ sí WO FÍDÍÒ LÓRÍṢIRÍṢI > ÀWỌN Ọ̀DỌ́.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 19 ìpínrọ̀ 17 sí 31, àpótí tó wà lójú ìwé 170 àti àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 171

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 123 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́