ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 November ojú ìwé 4
  • November 14 sí 20

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 14 sí 20
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 November ojú ìwé 4

November 14 Sí 20

Oníwàásù 1-6

  • Orin 66 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Gbádùn Gbogbo Iṣẹ́ Àṣekára Rẹ”: (10 min.)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Oníwàásù.]

    • Onw 3:12, 13​—Iṣẹ́ àṣekára jẹ́ ẹ̀bùn látọ̀dọ̀ Ọlọ́run, ó sì yẹ ká gbádùn rẹ̀ (w15 2/1 ojú ìwé 4 sí 6)

    • Onw 4:6​—Máa fi ojú tó tọ́ wo iṣẹ́ rẹ (w15 2/1 ojú ìwé 6 ìpínrọ̀ 3 sí 5)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Onw 2:10, 11​—Kí ni Sólómọ́nì wá mọ̀ nípa níní ọrọ̀? (w08 4/15 ojú ìwé 22 ìpínrọ̀ 9 àti 10)

    • Onw 3:16, 17​—Ojú wo ló yẹ ká máa fi wo ìwà ìrẹ́jẹ tó kúnnú ayé? (w06 11/1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 9)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Onw 1:1-18

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn wp16.6 tó wà lójú ìwé 2​—Fún un ní káàdì ìkànnì JW.ORG.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn wp16.6​—Ka ẹsẹ Bíbélì kan látorí fóònù tàbí tablet.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 22 àti 23 ìpínrọ̀ 11 àti 12​—Pe ẹni náà wá sí ìpàdé.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 140

  • “Bá A Ṣe Máa Lo Ìwé Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa? ”: (15 min.) Ìjíròrò. Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò bá a ṣe ń darí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, tó dá lórí Òtítọ́ 4 lójú ìwé 115 nínú ìwé Bíbélì Kọ́ Wa, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 4 ìpínrọ̀ 1 sí 6, àpótí náà “Ìtumọ̀ Orúkọ Ọlọ́run”

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 112 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́