ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 January ojú ìwé 3
  • January 9-15

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • January 9-15
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 January ojú ìwé 3

January 9-15

AÍSÁYÀ 29-33

  • Orin 123 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ọba Kan Yóò Jẹ fún Òdodo”: (10 min.)

    • Ais 32:1​—Jésù Kristi ni Ọba tó máa jẹ fún òdodo (w14 2/15 6 ¶13)

    • Ais 32:2​—Jésù tó ti di ọba pèsè àwọn ọmọ aládé tó máa bójú tó agbo rẹ̀ (ip-1 332-334 ¶7-8)

    • Ais 32:​3, 4​—Àwọn èèyàn Jèhófà ń rí ìtọ́ni àti ìdálẹ́kọ̀ọ́ gbà tó jẹ́ kí wọ́n lè jẹ́ olódodo (ip-1 334-335 ¶10-11)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ais 30:21​—Àwọn ọ̀nà wo ni Jèhófà ń gbà bá àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ sọ̀rọ̀? (w14 8/15 21 ¶2)

    • Ais 33:22​—Ìgbà wo ni Jèhófà di Onídàájọ́, Ẹni tí ń fúnni ní ìlànà àgbékalẹ̀, àti Ọba fún orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì, báwo ló sì ṣe dì í? (w14 10/15 14 ¶4)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 30:22-33

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn wp17.1​—Fún onílé tínú ń bí lésì.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn wp17.1​—Ka ẹsẹ Ìwé Mímọ́ látorí fóònù tàbí tablet.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 31-32 ¶12-13​—Ṣe àṣefihàn béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 119

  • “Ibi Ìfarapamọ́sí Kúrò Lọ́wọ́ Ẹ̀fúùfù” (Ais 32:⁠2): (9 min.) Jẹ́ káwọn ará wo fídíò yìí.

  • Máa Fetí Sílẹ̀ Nípàdé: (6 min.) Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Máa Fetí Sílẹ̀ Nípàdé. Lẹ́yìn náà, pe àwọn ọmọdé tó o ti yàn tẹ́lẹ̀ wá sórí pèpéle, kó o sì bi wọ́n láwọn ìbéèrè yìí: Kí ló lè mú kẹ́ ẹ má fetí sílẹ̀ nípàdé? Kí ló lè ṣẹlẹ̀ ká ní Nóà kò fetí sílẹ̀ nígbà tí Jèhófà ń ṣàlàyé bó ṣe máa kan ọkọ̀ áàkì fún un? Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì pé káwọn ọmọdé máa fetí sílẹ̀ nípàdé?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 6 ¶16-24 àti àpótí “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 40 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́