ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 January ojú ìwé 6
  • January 23-29

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • January 23-29
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 January ojú ìwé 6

January 23-29

Aísáyà 38-42

  • Orin 78 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jèhófà Ń Fi Agbára fún Ẹni Tó Ti Rẹ̀”: (10 min.)

    • Ais 40:25, 26​—Jèhófà ni Orísun gbogbo agbára (ip-1 409-410 ¶23-25)

    • Ais 40:27, 28​—Jèhófà ń rí gbogbo ohun tí à ń fara dà àti ìyà tó ń jẹ wá (ip-1 413 ¶27)

    • Ais 40:29-31​—Jèhófà máa ń fún àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé e lágbára (ip-1 413-415 ¶29-31)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ais 38:17​—Ọ̀nà wo ni Jèhófà ń gbà ju àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa sí ẹ̀yìn rẹ̀? (w03 7/1 18 ¶17)

    • Ais 42:3​—Báwo ni àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe ṣẹ sí Jésù lára? (w15 2/15 8 ¶13)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 40:​6-17

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 38-39 ¶6-7​—Ṣe àṣefihàn béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 68

  • “Máa Rántí Gbàdúrà Fáwọn Kristẹni Tí Wọ́n Ń Ṣe Inúnibíni Sí”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ wo fídíò náà Wọ́n Ní Káwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Pa Dà Sílé Ẹjọ́ Nílùú Taganrog​—Ìgbà Wo La Máa Bọ́ Báyìí?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí  7 ¶10-18, the box “Àwọn Ètò Orí Rédíò WBBR,” and the box “Àpéjọ Àgbègbè Mánigbàgbé”

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 9 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́