ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 February ojú ìwé 3
  • February 13-19

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • February 13-19
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 February ojú ìwé 3

February 13-19

Aísáyà 52-57

  • Orin 148 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Kristi Jìyà fún Wa”: (10 min.)

    • Ais 53:3-5​—Wọ́n tẹ́ńbẹ́lú rẹ̀, wọ́n sì tẹ̀ ẹ́ rẹ́ nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa (w09 1/15 26 ¶3-5)

    • Ais 53:7, 8​—Ó fẹ̀mí ara rẹ̀ rúbọ fún wa tinútinú (w09 1/15 27 ¶10)

    • Ais 53:11, 12​—Àwa náà lè ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú Ọlọ́run torí pé Jésù jẹ́ olóòótọ́ títí dójú ikú (w09 1/15 28 ¶13)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ais 54:1​—Ta ni “àgàn tí kò bímọ” tí àsọtẹ́lẹ̀ yìí tọ́ka sí, àwọn wo sì ni “àwọn ọmọ” rẹ̀? (w06 3/15 11 ¶2)

    • Ais 57:15​—Kí ni Jèhófà ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé òun ń “gbé” pẹ̀lú “àwọn tí a tẹ̀ rẹ́” àti “àwọn ẹni rírẹlẹ̀”? (w05 10/15 26 ¶3)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 57:1-11

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ll 6​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ll 7​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 14-15 ¶16-17​—Tó bá ṣeé ṣe, ẹ jẹ́ kí bàbá kan bá ọmọkùnrin tàbí ọmọbìnrin rẹ̀ kékeré ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 110

  • “Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ní Ìgbàgbọ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Nínú Ẹlẹ́dàá”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò yìí Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ​—Ọlọ́run Wà Lóòótọ́.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 8 ¶8-13 àti “Àtẹ Àwọn Ìwé Tí Wọ́n Ń Tẹ̀ Jáde Jù Láyé”

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 107 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́