ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 February ojú ìwé 6
  • February 27–March 5

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • February 27–March 5
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 February ojú ìwé 6

February 27–March 5

Aísáyà 63-66

  • Orin 19 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ọ̀run Tuntun àti Ayé Tuntun Máa Mú Ká Láyọ̀ Tó Kọ Yọyọ”: (10 min.)

    • Ais 65:17​—“Àwọn ohun àtijọ́ ni a kì yóò sì mú wá sí ìrántí” (ip-2 383 ¶23)

    • Ais 65:18, 19​—A máa láyọ̀ tó kọ yọyọ (ip-2 384 ¶25)

    • Ais 65:21-23​—A máa ní ìtẹ́lọ́rùn, ọkàn wa sì máa balẹ̀ (w12 9/15 9 ¶4-5)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ais 63:5​—Báwo ni ìhónú Ọlọ́run ṣe ń tì í lẹ́yìn? (w07 1/15 11 ¶6)

    • Ais 64:8​—Báwo ni Jèhófà ṣe ń lo àṣẹ tó ní gẹ́gẹ́ bí amọ̀kòkò wa? (w13 6/15 25 ¶3-)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 63:1-10

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ef 5:33​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Ti 5:8; Tit 2:4, 5​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

  • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 66:23; w06 11/1 30-31 ¶14-17​—Àkòrí: Pípàdé Pọ̀​—Ohun Kan Tí Kò Ní Yí Padà Nínú Ìjọsìn Wa

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 129

  • “Jẹ́ Kí Ìrètí Tó O Ní Máa Fún Ẹ Láyọ̀” (Ais 65:17, 18; Ro 12:12): (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Ẹ Máa Yọ̀ Nínú Ìrètí.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 9 ¶1-9, àtẹ “Ìbísí Kárí Ayé”

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 95 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́