ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 April ojú ìwé 6
  • April 17-23

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • April 17-23
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 April ojú ìwé 6

April 17-23

Jeremáyà 25-28

  • Orin 137 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jẹ́ Onígboyà Bíi Jeremáyà”: (10 min.)

    • Jer 26:2-6​—Jèhófà ní kí Jeremáyà kìlọ̀ fún àwọn èèyàn pé ìparun ń bọ̀ (w09 12/1 24 ¶6)

    • Jer 26:8, 9, 12, 13​—Jeremáyà ò gbà káwọn ọ̀tá kó jìnnìjìnnì bá òun (jr 21 ¶13)

    • Jer 26:16, 24​—Jèhófà dáàbò bo wolìí rẹ̀ tó jẹ́ onígboyà (w09 12/1 25 ¶1)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Jer 27:2, 3​—Kí ló lè fà á tí àwọn ońṣẹ́ láti oríṣiríṣi orílẹ̀-èdè fi wá sí Jerúsálẹ́mù, kí sì nìdí tí Jeremáyà fi ṣe ọ̀pá àjàgà fún wọn? (jr 27 ¶21)

    • Jer 28:11​—Báwo ni Jeremáyà ṣe lo làákàyè nígbà tí Hananáyà ta kò ó, kí nìyẹn sì kọ́ wa? (jr 187-188 ¶11-12)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 27:12-22

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-36​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-36​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 7 ¶4-5​—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 17

  • “Àwọn Orin Ìjọba Ọlọ́run Máa Ń Jẹ́ Ká Nígboyà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Orin Tó Ń Ru Àwọn Òṣìṣẹ́ Sókè.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 11 ¶9-21

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 26 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́