ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 December ojú ìwé 2
  • December 4-10

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 4-10
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 December ojú ìwé 2

December 4-10

SEFANÁYÀ 1–HÁGÁÌ 2

  • Orin 151 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ẹ Wá Jèhófà Kí Ọjọ́ Ìbínú Rẹ̀ Tó Dé”: (10 min.)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sefanáyà.]

    • Sef 2:​2,3​—Ẹ wá Jèhófà, ẹ wá òdodo,ẹ wá ọkàn-tútù (w01 2/15 18-19 ¶5-7)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Hágáì.]

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sef 1:8​—Ìkìlọ̀ wo ló wà nínú ẹsẹ Bíbélì yìí? (w07 11/15 11¶3)

    • Hag 2:9​—Àwọn ọ̀nà wo ni ògo tẹ́ńpìlì Serubábélì gbà ju ti tẹ́ńpìlì Sólómọ́nì lọ? (w07 12/1 9¶3)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Hag 2:1-14

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. ba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n fún ọ̀pọ̀ èèyàn ní ìwé ìròyìn GJí! No.6 2017. Àmọ́, torí pé a fẹ́ bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ ní tààràtà, a ò ní fi sí ẹnu ọ̀nà àwọn tí kò bá sí nílé.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 30

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)

  • Èdè Mímọ́ Tó Ń Mú Kí Àlàáfíà àti Ìṣọ̀kan Túbọ̀ Máa Gbilẹ̀ (Sef 3:9): (10 min.) Ìjíròrò tó dá lórí Ilé Ìṣọ́ August 15, 2012, ojú ìwé 12, ìpínrọ̀ 4. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, Ọ̀tá Ni Wọ́n Tẹ́lẹ̀, Àmọ́ Ọ̀rẹ́ Ni Wọ́n Báyìí.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 22 ¶8-16

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3min.)

  • Orin 136 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́