December 25-31
MÁLÁKÌ 1-4
Orin 36 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ṣé Ìgbéyàwó Rẹ Ń Múnú Jèhófà Dùn?”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Málákì.]
Mal 2:13,14—Jèhófà kórìíra kéèyàn máa ṣe àdàkàdekè nínú ìgbéyàwó (jd 125-126 ¶4-5)
Mal 2:15,16—Jẹ́ olóòótọ́ sí ọkọ tàbí aya rẹ (w02 5/1 18 ¶19)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Mal 1:10—Kí nìdí tó fi yẹ kó jẹ́ pé ìfẹ́ aláìmọtara-ẹni-nìkan tá a ní fún Ọlọ́run àti fún àwọn èèyàn ló ńmú ká jọ́sìn Ọlọ́run? (w07 12/15 27¶1)
Mal 3:1—Báwo ni ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe nímùúṣẹ ní ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní àti lákòókò yìí? (w13 7/15 10-11 ¶5-6)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mal 1:1-10
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Kọ 15:26—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 26:19; 2Kọ 1:3,4—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. (Wo mwb16.08 8 ¶2.)
Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w07 12/15 28 ¶1—Àkòrí: Báwo La Ṣe Lè Kó Gbogbo Ìdá Mẹ́wàá Wa Wá Sínú Ilé Ìtọ́jú Nǹkan Pa Mọ́ Lónìí?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?”: (15 min.) Ìbéèrè àti ìdáhùn.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 1 ¶10-18, àpótí tó wà lójú ìwé 13 [Kò pọn dandan kẹ́ ẹ jíròrò àpótí tàbí àfikún àlàyé]
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3min.)
Orin 114 àti Àdúrà